IROIDUNNU RADIO
IROIDUNNU RADIO

IROIDUNNU RADIO

IROIDUNNU RADIO is an online radio operating from the city of Lagos, we broadcast primarily in Yoruba language. Our mission is to exhibit the beauty of Yoruba language and cultures through our broadcast content.

Announcement

December 22, 2021

OBÌRIN NI MÍ pẹ̀lú Kẹ́mi Akíntáyọ̀

Ẹ tẹ́tí sí ètò OBÌRIN NI MÍ ( I AM A WOMAN) ní alẹ́ ọ̀la, lórí Rédíò Ìróidùnnú, ni déédéé Agogo Mẹ́sàn Alẹ́ (9PM WAT). Olúwakẹ́mi Akíntáyọ̀ ni atọ́kùn ètò. Àkòrí ètò lọ́sẹ̀ yí; OÚNJẸ FÚN ARA ÀTI ỌPỌLỌ TÍ Ó JÍ PÉPÉ (IDEAL FOOD FOR HEALTHY BODY AND MIND) Àlejò wa lọ́sẹ̀ yí ni Ronke Aya Adeduntan.